Ifeking – Se Rere

Se Rere – Ifeking Lyrics Letra:
(Verse)
Orisa jen pe meji obirin kodenu
Oun yanle, si be olonifere gidigan
Seku seye, aoti seyisi
Iwo loun se, iwo loun gba, abosi oda(Chorus)
Eje ka se rere
Rere lope .
Eje ka se rere
Ika oda /repeated(Verse)
Igba amayi folowo
Igba asimayi fo loro
Gbogbo unkan lonigba
atasiko ti re oooo
Oremi kilo fi igbarese

(Chorus)
Eje ka se rere
Rere lope
Eje ka se rere
Ika oda /repeated(Bridge)
Esan ake oooo
Esan ma un bo ooo
Esan ake oooo
Esan ma un bo ooo
Lati san folukuluku
eniyan
Gege bi ise owo retiri
Esan ake oooo
Esan maun bo oooo
Esan ake ooooo
Esan maun bo oooo
Eje kase rere eeee
Rere lope eeee

(Chorus)
Eje kase rere eeee
Ika omada ore mi
Eje kase rere eee
Rere lope eeeee
Eje kase rere eee
Ika oda rara oooo
Eje kase rere eee
Ika oda aaaaa
Letra lyrics lyric letras versuri musiek lirieke tekstet paroles

%d blogueiros gostam disto: